mail me lyrics Send Lyrics Updates into my email! (feedburner)

Kuse - Lyrics/Video/Download - Psalmos Feat. Kenny K'ore



Mo wo waju mi, mo ri owo Yin
Mo w'eyin wo, mo ri ife Yin
Won wa bere lo wo mi pe bawo ni mo se se
Mo so fun won wipe

Emi naa ko o
Olorun Oba ma ni
Olorun Oba ma ni
Olorun Oba ma ni

Emi na ko o,
Olorun Oba ma ni
Olorun Oba ma ni
Olorun Oba ma ni

Moni Baba kan o
Moni Baba kan o
Baba Ara to mo iyi omo
Moni Baba kan o
Moni Baba kan o
Baba Ara to mo iyi omo

Moni Baba kan o
Moni Baba kan o
Baba Ara to mo iyi omo

Moni Baba kan o
Moni Baba kan o
Baba Ara to mo iyi omo

Moni Baba kan o
Moni Baba kan o
Baba Ara to mo iyi omo

Moni Baba kan o
Moni Baba kan o
Baba Ara to mo iyi omo



Verse I
Oluwa ku ise
Eee
Ku ise
E e
Ku ise
Oo

Oluwa ku ise o
E e e
Ku ise

Oni kan bi o subu mo ro bi oo
(elo o se ye)
Eterete o Baba ku ise o
Oni ko bi o subu mo ro bi oo
(elo o se ye)
Eterete o Baba ku ise
Oni ko bi o su bu mo ro bi oo
(elo o se ye)
Eterete o Baba ku ise

Oluwa ku ise
Iba mi ku ise
Oluwa ku ise
Iba mi ku ise

Ku ise,
Ku ise
Ku ise
Ku ise
Ku ise

Oni ko bi o subu mo ro bi oo
Eterete o Baba ku ise o
Oni ko bi o subu mo ro bi oo
Eterete o Baba ku ise
Oni ko bi o su bu mo ro bi oo
Eterete o Baba ku ise

Mo de wa so pe
Ni mo de wa so pe oo
Mo de wa so pe
Ni mo de wa so pe oo

Oni kan se lore, ki ye mo
Onubi oni
Emi kan se lore ki mo mo
Mo de ya sope oo


Kenny K'ore
En en
B'olode o ba ku
Ojude re ki n hu koriko
Ko sai s'eyin Olubori
Atofaratibioke

Ti Emi
A lemi naa ni
Ti mo fi g'oke odo k'afara o to ja
Ara e fi oju ire wo mi
Eniyan e fi owo anu kan mi
Emi na ko
Eledumare ni
Olorun mi a
Baba mi

Eledumare
Ogbagba tii gba alailara
Oba aa ji ki
Oba aa ji ri
Oba aidigbolu
Eni digbolu O, a si run womuwomu


Oni ko bi o su bu mo ro bi oo
Eterete ooo Baba ku ise

Oni kan wi o subu
maro guro ehhh
maro guro ehhh
Oooo…ooooooooooo

Mo de ya sope
Mo de ya sope
Mo de ya sope
Mo de ya sope




  • All Artistes Index
  • Random Posts

    No comments:

    Post a Comment

    Newer Post Older Post Home