mail me lyrics Send Lyrics Updates into my email! (feedburner)

Ijoba Orun - Lyrics/Download [with translation in English] - Lara George


Ijoba Orun lere onigbagbo o
Ijoba Orun lere onigbagbo o
Ma je n kuna
Baba Mumi dele o
Ma je n kuna, Baba se
Mumi dele o
Owo ti mo ni ko le mumi dele o
Moto ti mo ri ra
Ko le wa mi de le o
Ore ti mo ni
Ko le sinmi de le o
Gbogbo iwe ti mo ri ka
Won o le gbe mi de le o
Ma je n kuna
Baba
Mumi de le o
Ki ma ku s’ajo bi efin
Mumi de le o
Aye l’oja
Orun nile
Mumi de le o
Aye l’oja
Orun nile see
Mumi dele o

Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)

Ma ma je n kuna
Baba oooo
Baba oooo
Mumi dele o
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Ile ogo
Ile ayo
Ile ayo
Ile Alafia
Ile ogo

Ijoba Orun l’ere onigbagbo o
Ijoba Orun lere onigbagbo o
Ma je n kuna

Yoruba-English Language translation
Ijoba Orun lere onigbagbo o [the kingdom of heaven is the reward of the believer]
Ma je n kuna [don’t let me miss it]
Baba Mumi dele o [Father, take me home]
Ma je n kuna, Baba se
Mumi dele o
Owo ti mo ni ko le mumi dele o [my money cannot take me home]
Moto ti mo ri ra, Ko le wa mi de le o [the car that I bought cant drive me home]
Ore ti mo ni [the friend I have]
Ko le sinmi de le o [can’t see me off home]
Gbogbo iwe ti mo ri ka [all my academic qualiications]
Won o le gbe mi de le o [none can get me home]
Ma je n kuna [don’t let me miss it]
Baba
Mumi de le o [take me home]
Ki ma ku s’ajo bi efin [that I do not faint by the way]
Mumi de le o
Aye l’oja [the earth is only a marketplace]
Orun nile [heaven is home]
Mumi de le o
Aye l’oja
Orun nile see
Mumi dele o

Mu mi dele o [take me home]
(Dele, dele)
Ile ogo [home of glory]
Ile ayo [home of joy]
Ile ayo
Ile Alafia [home of peace]
Ile ogo

 
Click to download song


  • All Artistes Index
  • Random Posts

    1 comment:

    Newer Post Older Post Home