mail me lyrics Send Lyrics Updates into my email! (feedburner)

Aye Ole - Lyrics/Download - Infinity



Hmmmm
Omo eniyan
F'eti si
Oro agba, bi o se l'owuro
A se lowo ale

Verse I
Bowu ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d'opin
Aimola eda lo mu eda s’aniyan ola
Olorun ti seleri, oro Baba ko ni ye
Ainigbagba lo mu eda r’aropin
Bi okun n fo
Ti osa n sa
Otito wa laaye
Igbagbo ni orisun ohun gbogbo

Chorus
Oh huu huuu aye yi ko male
Aye ole f’eni to nigbagbo p’aye ole
Oh huu huuu aye yi ko male
Aye ole f’eni to nigbagbo p’aye ole
Oh huu huuu aye yi ko male
Aye ole f’eni to nigbagbo p’aye ole
Oh huu huuu aye yi ko male
Aye ole f’eni to nigbagbo p’aye ole

Verse II
Onisuuru, apekotojeun, koni jebaje
Aimanisuuru lo n mu are eni bo wa debi
F'oju re wo mi ore, k'Oluwa le foju re wo e
Abiku ti d'abiye ninu aye mi
Onisuuru, apekoto je, koni jebaje
Aimani suuru lo n mu are eni bo wa d’ebi
F'oju re womi ore, k'Oluwa le foju re wo e
Abiku ti d'abiye ninu aye mi

Chorus


Ha ha haa
Aye re ko ma ni le
Ha ha haa, To ba ba Olorun rin, o soriire
Ha ha haa
Aye re ko ma ni le
Ha ha haa, To ba ba Olorun rin, o soriire
Ha ha haa
Aye re ko ma ni le
Ha ha haa, To ba ba Olorun rin, o soriire
Ha ha haa
Aye re ko ma ni le
Ha ha haa, To ba ba Olorun rin, o soriire

Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d'opin


Download Song


  • All Artistes Index
  • Random Posts

    No comments:

    Post a Comment

    Newer Post Older Post Home