mail me lyrics Send Lyrics Updates into my email! (feedburner)

Nigerian Yoruba Church Praise songs

Kabiesi, Oba gbogbo aye

Kabiyesi, Oba gbogbo aye
Kabiesi, Oba gbogbo aye
Baba Ese gan an

Alagbara bi ara o, Eya Judah

Alagbara bi ara o, eya Judah
Kiniun de, Eya Judah

Oba Alade Wura de

O de, O de,
Oba Alade wura de

Kilo mu t'omiwa?

kilo mu tomiwa?
ohun rere lo mu tomiwa
o le iku w'ogbo
O le aarun w'ole
O wa so'banuje mi dayo
Ohun rere lO'mu tomiwa
Abi beeko o?
Aaah, Bee naa ni
Aye mi dara o
Aah, Bee naa ni

Ti mba sop'Olorun o see to

Ti mba sop'Olorun o see to
Ti mba sop'Olorun o see to
Ti mba sop'Olorun o see to o
Abaramooreje ni mi o eeh

Olore ofe, Eleruniyin
Olorun otito
Mo gbe o ga

Jesu Oloore o... Oloore
Messiah Oloore o... Oloore
Jesu Oloore o... Oloore
Messiah Oloore o... Oloore
O ku nitori mi.... Oloore
O jiya nitori mi o... Oloore
E wa bami gboroyin yi, Iroyin ayo, Iroyin rere
E wa bami gboroyin yi, Iroyin ayo, Iroyin rere
Iroyin toju'royin lo... Iroyin ayo, Iroyin rere

Alayo ni mi
Emi  yoo mayo
Jesu layo mi
Ewa bamiyo

Alaaye  ni o maa yin O o Baba
Alaaye  ni o maa yin O o Omo
Eni to ti ku kolee yin O
Alaaye  ni o maa yin O o Baba
Eni to ti ku kolee yin O
Alaaye  ni o maa yin O o Baba

Kabiyesi Re Iwo lOba
Kabiyesi Re Iwo lOba
Ko mama s’Oba bi Ire
Kabiyesi Re Iwo lOba

Alaayo ni mi
Emi yoo maa yo
Jesu layo mi
Ewa bamiyo

Nigba ti mo ro
Tife Re laye mi Jesu
Nigba ti mo ro
T'aanu Re O jo mi loju

Fehinti fehinti
Jesu ni mo fehinti
Jesu ni mo fehinti
mi o le subu

Fehinti fehinti
Jesu ni mo fehinti
Jesu ni mo fehinti
mi o le subu
Rara rara, mi o le subu
Rara rara, mi o le subu
Fehinti fehinti
Jesu ni mo fehinti
Jesu ni mo fehinti
mi o le subu



  • All Artistes Index
  • Random Posts

    No comments:

    Post a Comment

    Newer Post Older Post Home