Jesu Onirele,
Omo Olorun :
Alaanu, Olufe,
Gbo ‘gbe omo Re.
Fi ese wa ji wa,
Si da wa n’ ide;
Fo gbogbo orisa
Ti mbe l’ okan wa.
Fun wa ni omnira,
F’ ife s’ okan wa ;
Fa wa Jesu mimo,
S’ ibugbe l’ oke.
To wa l’ ona ajo,
Si je ona wa
La okun aiye ja
S’ imole orun.
Jesu onirele,
Omo Olorun ;
Alaanu, Olufe,
Gbo ‘gbe omo Re. Amin.
Omo Olorun :
Alaanu, Olufe,
Gbo ‘gbe omo Re.
Fi ese wa ji wa,
Si da wa n’ ide;
Fo gbogbo orisa
Ti mbe l’ okan wa.
Fun wa ni omnira,
F’ ife s’ okan wa ;
Fa wa Jesu mimo,
S’ ibugbe l’ oke.
To wa l’ ona ajo,
Si je ona wa
La okun aiye ja
S’ imole orun.
Jesu onirele,
Omo Olorun ;
Alaanu, Olufe,
Gbo ‘gbe omo Re. Amin.
Very inspiring
ReplyDelete