A f’ope f’ Olorun,
L’ okan ati ohun wa,
Eni s’ ohun ‘yanu,
N’nu Enit’ araiye nyo;
Gbat’ a wa l’ om’owo
On na l’ o ntoju wa
O si nf’ ebun ife
Se 'toju wa sibe.
Oba Onib'ore
Ma fi wa sile lailai
Ayo ti ko lopin
On 'bukun y'o je tiwa;
Pa wa mo n'nu ore,
To wa gb' a ba damu,
yo wa ninu ibi
Laiye ati l'orun.
K' a f' iyin on ope
F' Olorun Baba, Omo,
Ati Emi mimo;
Ti o ga julo l' orun,
Olorun kan lailai,
T'aiye at'orun mbo,
Be l'o wa d'isiyi,
Beni y'o wa lailai. Amin
L’ okan ati ohun wa,
Eni s’ ohun ‘yanu,
N’nu Enit’ araiye nyo;
Gbat’ a wa l’ om’owo
On na l’ o ntoju wa
O si nf’ ebun ife
Se 'toju wa sibe.
Oba Onib'ore
Ma fi wa sile lailai
Ayo ti ko lopin
On 'bukun y'o je tiwa;
Pa wa mo n'nu ore,
To wa gb' a ba damu,
yo wa ninu ibi
Laiye ati l'orun.
K' a f' iyin on ope
F' Olorun Baba, Omo,
Ati Emi mimo;
Ti o ga julo l' orun,
Olorun kan lailai,
T'aiye at'orun mbo,
Be l'o wa d'isiyi,
Beni y'o wa lailai. Amin
No comments:
Post a Comment